image
image

2026 ÀSỌTẸ́LẸ̀ NÍPA OJÚ ỌJỌ́

Topic: SCP

Document Type: SCP

NiMet
Download counts 1

Àsọtẹ́lẹ̀ ojú ọjọ́ ọdún 2026 ní ò dá lórí àìkò lágbára La Nina àti bí kò se sí nǹkankan láti ọ̀dọ̀ El Nino Southern Oscillation ìgbà tí ó seése kí òjò tètè bẹ̀rẹ̀ saájú àkókò òjò lọ títí di ìgbà tí yóò dá ju bí ò se máa ń rí tẹ́lẹ̀ lọ, pẹ̀lú bí ó se seése kí òjò pọ̀ àti bí sáà kan yóò sé gun tò, irú atẹ́gùn tí yóò fẹ́ ju bí ó se máa ń rí tẹ́lẹ̀ lọ́ ní àwọn apá ibìkan ní orílẹ̀èdè yìí, Nǹkan tí a ń sọ ni wípé ìgbà tí sáà òjò yóò bẹ̀rẹ̀, ati ìgbà tí ó seése kó parí. Bí sáà kan yóò se gùn tó ni ó ń se àpèjúwè láàrín ìgbà tí yóò bẹ̀rẹ̀ àti ìgbà tí yóò parí.

NiMet Weather Assistant

NiMet Weather Assistant

Get expert insights on Seasonal Climate Predictions

Welcome to NiMet Assistant

Ask me anything about Seasonal Climate Predictions or general weather information